Barry Jhay – Bless Me Lyrics
Yeah-yeah, ah-ahh, ah
Shi’ju anu wo mi oh, Eledumare, Baba
Oh-ahh-ayy, ah-ayy
Ayy, na-na (ayy, na-na)
T’omode, t’agbalagba lo w’oju rere e
Ukwu ukwu, ukwu gan w’oju rere e
Eni toh l’owo ati eni o ni, won w’oju rere e
Kos’ohun t’ole shey, kos’ohun toh poju fun o lati shey
Iwo sha l’Oba, kosi Oba mi ran leyin re, leyin re oh
Kosi elomiran, Baba bless me, yeah-oh
Baba jowo, bless me, ah-ah
Olu orun, nibo l’oju re wa? ayy-ayy, ayy
A fe r-e-e-ti re oh, Baba
Olu orun yeah, nibo l’oju re wa? ayy
A fe r-e-e-ti re oh
Olu orun, nibo l’oju re wa? ayy-ayy, ayy
A fe r-e-e-ti re oh, Baba
Olu orun yeah, nibo l’oju re wa? ayy
A fe r-e-e-ti re oh
Iwo lo sh’oko fun opo
Iwo ni Baba lai ni baba, ayy, oh-ah
Iwo ni ma pe ti wahala ba de
Kosi elomiran afi iwo, oh-oh, afi iwo
Maje k’oju ti omo
T’omode, t’agbalagba lo w’oju rere e
Ukwu ukwu, ukwu gan w’oju rere e
Eni toh l’owo ati eni o ni, won w’oju rere e
Kos’ohun t’ole shey, kos’ohun toh poju fun o lati shey
Iwo sha l’Oba, kosi Oba mi ran leyin re, leyin re oh
Kosi elomiran, Baba bless me, yeah-oh (ibo l’oju re wa?)
Baba jowo, bless me, ah-ah
Olu orun, nibo l’oju re wa? ayy-ayy, ayy
A fe r-e-e-ti re oh, Baba
Olu orun yeah, nibo l’oju re wa? ayy
A fe r-e-e-ti re oh
Olu orun, nibo l’oju re wa? ayy-ayy, ayy
A fe r-e-e-ti re oh, Baba
Olu orun yeah, nibo l’oju re wa? ayy
A fe r-e-e-ti re oh
Eni o l’oju, o fun l’oju t’ofi ri ran
Eni o l’enu, ishee le fun l’enu k’ofi s’oro
Eni o l’eti, e fun l’eti k’ofi gbo’ran
Eni o l’ori ro, ishee le ya l’opolo
T’omode, t’agbalagba lo w’oju rere e
Ukwu ukwu, ukwu gan w’oju rere e
Eni toh l’owo ati eni o ni, won w’oju rere e
Kos’ohun t’ole shey, kos’ohun toh poju fun o lati shey
Iwo sha l’Oba, kosi Oba mi ran leyin re, leyin re oh
Kosi elomiran, Baba bless me, yeah-oh
Baba jowo, bless me, ah-ah
Olu orun, nibo l’oju re wa? ayy-ayy, ayy
A fe r-e-e-ti re oh, Baba
Olu orun yeah, nibo l’oju re wa? ayy
A fe r-e-e-ti re oh
Olu orun, nibo l’oju re wa? ayy-ayy, ayy
A fe r-e-e-ti re oh, Baba
Olu orun yeah, nibo l’oju re wa? ayy
A fe r-e-e-ti re oh
Daddy, with you-‘ou-‘ou
Nothing is impossible, ehn-ehn
Daddy, you’re powerful, ehn-ehn oh
Nothing wey you no fit do
Ah-ayy, ayy